DOWNLOAD HERE

DIOCESAN PRAYER

O Lord our God and owner of the Church, thank you for the Diocese of Owo and the labourers of its heroes past; have mercy on this Diocese; forgive its past, heal its foundation, provide for its members at home and abroad, protect its members; hide its shame and bless its members with generosity of heart that they may joyfully serve you in every generation. May the light of the Gospel shine to dispel every form of darkness.

Help its Bishop, Clergy and People that they may be diligent and faithful in proclaiming your words and in bringing hope and comfort to the weak, sick, poor and needy in the community.

Where there is division give unity, where there is trouble give peace, revive the church

that it may be faithful in its service and make progress in all good things through the might of Jesus Christ our Lord and Saviour. Amen.

ADURA FUN DAOSISI

Oluwa Olorun wa ati Oluwa Ijo, adupe lowo Re fun Daosisi Owo ati fun ise ti awon akoni isaju tise; Saanu fun Daosisi yi, dari gbogbo ese atehinwa ji i, wo ipile re san, pese fun awon omo ijo nile ati nidale, dabobo won; mu egan re kuro, ki osi fi ibukun okan isoore fun awon omo ijo, ki won le ma fi tayotayo sin O lati iran d’iran. Je ki imole ihinrere tan lati tu gbogbo ipa okunkun ka.

Ran Bisobu, awon Alufa ati Eniyan re lowo ki won le je alaapon ati olotito ninu kikede oro Re, ati ninu mimu ireti ati itura ba alare, alaisan, otosi, alaini ati talaka ni awujo.

Nibiti iyapa ba gbe wa; fun wa ni isokan; Nibiti wahala ba gbe wa; fun wa ni alaafia, so ijo re ji ki o le je olotito ninu ise isin re, ki o si ma tesiwaju ninu ohun rere gbogbo nipa agbara Jesu Kristi Oluwa ati Olugbala wa. Amin.

(Copmosed by: Bishop S. Ayodeji Fagbemi)

%d bloggers like this: