Owo Daosisi a ki o
Je-su ni ipinle Re
Lori apata la ko si
Emi ife ati isokan
La nsise Oluwa
Eyin omo ogun Kristi
E fi ‘gbagbo jagun
E korin ife s’Oluwa
Ore-Ofe Oluwa
Ko wa pelu Owo Daosisi.

DOWNLOAD THE AUDIO VERSION