MISSION

 1. To prepare, train equip and support the clergy and leadership of the Diocese
 2. As an evangelical, charismatic Anglican Diocese where the Gospel is preached and spiritual gifts encouraged.
 3. Caring for and empowering our members in preparing all for the kingdom of God through holy living
 4. Reach every community with the gospel of Christ, offering hope to the youths and elders alike.
 5. Equipping the clergy
 6. Reaching the community
 7. Caring for all

VISION 
Our vision is to be united in love to occupy our rightful position within the church of Nigeria, to reach the world with the gospel and care for all, where every soul matters.

Slogan: Arise and Shine

IRAN DAOSISI
Iran wanilati je okanninuife, latigbaipoti o to siwalarinijotiNaijiria, lati mu ihinrere to gbogboaraiyeatilati se itojueniyangbogbo, nibitigbogbookanti je Pataki

ISE WA

 1. Lati se igbaradi, idaleko, itojuatiatileyin fun awon Alufa ati awon asoju ni Daosisi
 2. Gege bi DaosisionihinreretiijoAnglikanti o mu oroOlorungirigiriti o sifiyesioniruruebun Emi Olorun
 3. Lati se itojuatiirolagbara fun awonomoijoniimurasilefunijobaOlorunnipaigbe aye iwamimo
 4. Lati mu Ihinrere Kristi to gbogboolugbeagbegbe, ki a si mu ireti baa won odo ati agba bakanna
 5. Latipese fun ojoiwaju
  • Ipese fun awonAlufa
  • Jijadesiagbegbe
  • Siseitojueniyangbogbo

Oro Apele: Dideki o tan imole

%d bloggers like this: